Posted On: October 11th 2026, 04:48 pm
TAKE CAUTION OF BOLTON PERCUSSION
Baba wa tí ń bẹ ní òrun
Kí a bowò fún orúkọ Re
Kí ijoba Re dé
Ifé Tirẹ ni kí a șe láyé
Bí wọn ti ń se ní òrun
Fún wa l’óúnjẹ òòjó wa lónìí
Dárí èsè wa jì wá
Bí a tií dárí èsè ji àwọn tó sè wá
Má fàwá sínú ìdánwò
Şùgbón gbà wá lówó bìlísì
Nítorí ijoba ni Tire
Agbára ni Tire
Ògo ni Tire
Láyé àti Láéláé
AMIN
Load More